🇳🇬 Nigeria Gospel

Tope Alabi – L’oro L’ero Ati Ni’se

Follow Us On 👇
WHATSAPP GROUPTELEGRAM CHANNEL

Tope Alabi – L’oro L’ero Ati Ni’se, mp3 Download, Audio, song, music

Tope Alabi – L’oro L’ero Ati Ni’se

Nigerian Christian/Gospel Artiste Tope Alabi Released a New Single Titled “L’oro L’ero Ati Ni’se”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit.

DOWNLOAD MP3

L’oro L’ero Ati Ni’se (Lyrics) – Tope Alabi
Verse 1
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

Chrous:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Verse 2
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

Verse 3
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button