Tope Alabi – Jesu Ore Otito, mp3 Download, Audio, song, music
Gospel Artiste Tope Alabi Released a New Single Titled “Jesu Ore Otito”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit.
Jesu Ore Otito (Lyrics) – Tope Alabi
Verse 1
Wa sodo re yio gba o
Oun nikan ni mole to tan so kunkun
Oro re iye, o n gba ni la
Ko tun sona miran tole gbani
Chorus
Jesu jesu ore otito
Jesu kristi iye loro re
Otan mole so kunkun u aye wa
Enito gba jesu loni iye.
Verse 2
Wa ma sonu, aye jin na
Oun nikan lole rin o sebute
Aye so kunkun, jesu ni mole
Gbagbo yio mu o debi isimi
Verse 3
Faye re fun, fokan re fun
Mase je kona re mo loju re
Oluwa n kan lekun, ore ma se aya
Ayo la o fi ba jesu joba
Verse 4
Oun adun ni keru wiwo di itan
Alafia ti aye kori ni
Ifokanbale irorun, eyi to logo
La jogun fawon toluwa gbala
Leave a Reply