🇳🇬 Nigeria Gospel

Tope Alabi – E Yin Oluwa, Halleluyah

Follow Us On 👇
WHATSAPP GROUPTELEGRAM CHANNEL

Tope Alabi – E Yin Oluwa, Halleluyah, mp3 Download, Audio, song, music

Tope Alabi – E Yin Oluwa, Halleluyah

Gospel Artiste Tope Alabi Released a New Single Titled “E Yin Oluwa, Halleluyah”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit.

DOWNLOAD MP3

E Yin Oluwa, Halleluyah (Lyrics) – Tope Alabi
Verse 1
Eje ka f;ope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipa a re po o e
Bela nu re duro o lailai

Chorus:
Eyin o Oluwa o Halleluyah
Egbe e ga o o o o o Halleluyah
Eyin Oluwa o Halleluyah
O n logaju o o o o Halleluyah

Verse 2
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti kerubu sarafu korin si o
Oun re ru awon omi okun

Verse 3
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori dodo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo

Verse 4
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button