Tope Alabi – Ba Eleda Laja, mp3 Download, Audio, song, music
Gospel Artiste Tope Alabi Released a New Single Titled “Ba Eleda Laja”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit.
Ba Eleda Laja (Lyrics) – Tope Alabi
Verse 1
Asan laye ati nkan gbogbo
To nwu libi i wura didan
Kole gbeni nu etan aye
Owo ofo la o pada lo
Chorus
Ki o towo iwo orun
Ki o tode Iwo osupa
Emi a beleda mi laja
Verse 2
Igba a lo bi agogo
Odo wa n sise e ewu
O nsun mowa eda ko kaakun
Se giri ero o nbo dede
Verse 3
Bi sun re bada ohun lomi
Baye bata ni afa o mora
Ife re ju tara atebi
Isun re dara yo sun aigbe
Verse 4
Tete ba eleda laja
Korun towo kosupa tode
Ko yi pada lona egbe
Olugbala lo npe o wa
Leave a Reply